Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 9:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Johanu wá sọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n bi í pé, “Kí ló dé tí àwa ati àwọn Farisi ń gbààwẹ̀ ní ọ̀pọ̀ ìgbà, ṣugbọn àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ kì í gbààwẹ̀?”

Ka pipe ipin Matiu 9

Wo Matiu 9:14 ni o tọ