Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 9:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ lọ kọ́ ìtumọ̀ gbolohun yìí: Ọlọrun sọ pé, ‘Àánú ṣíṣe ni mo fẹ́, kì í ṣe ẹbọ rírú.’ Nítorí náà kì í ṣe àwọn olódodo ni mo wá pè, bíkòṣe àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀.”

Ka pipe ipin Matiu 9

Wo Matiu 9:13 ni o tọ