Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 9:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu dá wọn lóhùn pé, “Àwọn ọ̀rẹ́ ọkọ iyawo kò lè máa ṣọ̀fọ̀ níwọ̀n ìgbà tí ọkọ iyawo bá wà lọ́dọ̀ wọn. Àkókò ń bọ̀ nígbà tí a óo gba ọkọ iyawo lọ́wọ́ wọn; wọn yóo máa gbààwẹ̀ nígbà náà.

Ka pipe ipin Matiu 9

Wo Matiu 9:15 ni o tọ