Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 20:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sọ fún wọn pé, “Lódodo ẹ óo mu ninu ife mi, ṣugbọn láti jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún mi ati ní ọwọ́ òsì mi kò sí ní ìkáwọ́ mi láti fi fún ẹnikẹ́ni, ipò wọnyi wà fún àwọn tí a ti pèsè rẹ̀ sílẹ̀ fún láti ọ̀dọ̀ Baba mi.”

Ka pipe ipin Matiu 20

Wo Matiu 20:23 ni o tọ