Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 20:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu dáhùn pé, “Ẹ kò mọ ohun tí ẹ̀ ń bèèrè. Ẹ lè mu ninu ife ìrora tí èmi yóo mu?”Wọ́n dá a lóhùn pé, “A lè mu ún.”

Ka pipe ipin Matiu 20

Wo Matiu 20:22 ni o tọ