Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 12:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọbabinrin láti ilẹ̀ gúsù yóo ko ìran yìí lójú ní ìdájọ́ yóo sì dá a lẹ́bi. Nítorí ó wá láti ọ̀nà jíjìn láti gbọ́ ọgbọ́n Solomoni. Ẹ wò ó, ẹni tí ó ju Solomoni lọ ló wà níhìn-ín.

Ka pipe ipin Matiu 12

Wo Matiu 12:42 ni o tọ