Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 12:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Ninefe yóo ko ìran yìí lójú ní ìdájọ́, wọn yóo sì dá a lẹ́bi. Nítorí wọ́n ronupiwada nítorí iwaasu tí Jona wà fún wọn. Wò ó, ẹni tí ó ju Jona lọ ló wà níhìn-ín.

Ka pipe ipin Matiu 12

Wo Matiu 12:41 ni o tọ