Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 12:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí bí Jona ti wà ninu ẹja ńlá fún ọjọ́ mẹta tọ̀sán-tòru, bẹ́ẹ̀ ni Ọmọ-Eniyan yóo wà ninu ilẹ̀ fún ọjọ́ mẹta, tọ̀sán-tòru.

Ka pipe ipin Matiu 12

Wo Matiu 12:40 ni o tọ