Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 16:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ati pé ọ̀gbun ńlá kan wà láàrin àwa ati ẹ̀yin, tí ó fi jẹ́ pé àwọn tí ó bá fẹ́ kọjá sí ọ̀dọ̀ yín kò ní lè kọjá; bákan náà àwọn tí ó bá fẹ́ ti ọ̀hún kọjá wá sí ọ̀dọ̀ wa kò ní lè kọjá.’

Ka pipe ipin Luku 16

Wo Luku 16:26 ni o tọ