Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 16:25 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣugbọn Abrahamu dá a lóhùn pé, ‘Ọmọ, ranti pé nígbà tí o wà láyé, kìkì ohun rere ni o gbà, nígbà tí ó jẹ́ pé nǹkan burúkú ni Lasaru gbà. Nisinsinyii, ìdẹ̀ra ti dé bá Lasaru nígbà tí ìwọ ń jẹ̀rora.

Ka pipe ipin Luku 16

Wo Luku 16:25 ni o tọ