Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 22:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Lọ́jọ́ keji, ọ̀gágun náà tú Paulu sílẹ̀. Ó fẹ́ mọ òtítọ́ ẹ̀sùn tí àwọn Juu mú wá nípa rẹ̀. Ó bá pàṣẹ pé kí àwọn olórí alufaa ati gbogbo ìgbìmọ̀ péjọ. Ó bá mú Paulu lọ siwaju wọn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 22

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 22:30 ni o tọ