Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 22:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹsẹkẹsẹ ni àwọn tí wọ́n fẹ́ wádìí ọ̀rọ̀ lẹ́nu rẹ̀ bá bìlà. Ẹ̀rù wá ba ọ̀gágun náà nígbà tí ó mọ̀ pé ọmọ-ìbílẹ̀ Romu ni Paulu, àtipé òun ti fi ẹ̀wọ̀n dè é.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 22

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 22:29 ni o tọ