Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 29:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn olórí ogun Filistini bèèrè pé, “Kí ni àwọn Heberu wọnyi ń ṣe níbí?”Akiṣi sì dá wọn lóhùn pé, “Ṣebí Dafidi, iranṣẹ Saulu ọba Israẹli nìyí, ó ti wà lọ́dọ̀ mi láti ìgbà pípẹ́, n kò tíì rí àṣìṣe kan lọ́wọ́ rẹ̀ láti ìgbà tí ó ti dé ọ̀dọ̀ mi títí di òní yìí.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 29

Wo Samuẹli Kinni 29:3 ni o tọ