Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 27:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Akiṣi bá bèèrè pé, “Àwọn wo ni ẹ kógun lọ bá lónìí?” Dafidi á sì dáhùn pé, “Ìhà gúsù Juda ni, tabi kí ó sọ wí pé ìhà gúsù Jerameeli tabi ìhà gúsù Keni.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 27

Wo Samuẹli Kinni 27:10 ni o tọ