Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 27:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi kò dá ẹnìkankan sí yálà ọkunrin tabi obinrin kí wọ́n má baà mú ìròyìn ohun tí ó ṣẹlẹ̀ lọ sí Gati, bẹ́ẹ̀ ni Dafidi ń ṣe ní gbogbo ìgbà tí ó ń gbé ààrin àwọn ará Filistia.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 27

Wo Samuẹli Kinni 27:11 ni o tọ