Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 26:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu dáhùn pé, “Mo ti ṣe ibi, máa bọ̀ Dafidi, ọmọ mi. N kò ní ṣe ọ́ ní ibi mọ́, nítorí pé ẹ̀mí mi níye lórí lójú rẹ lónìí. Mo ti hùwà òmùgọ̀, ohun tí mo ṣe burú pupọ.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 26

Wo Samuẹli Kinni 26:21 ni o tọ