Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 26:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Má jẹ́ kí n kú sílẹ̀ àjèjì níbi tí OLUWA kò sí. Kí ló dé tí ọba Israẹli fi ń lépa èmi kékeré yìí, bí ẹni ń dọdẹ àparò lórí òkè?”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 26

Wo Samuẹli Kinni 26:20 ni o tọ