Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 25:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Jọ̀wọ́ má ṣe ka aláìmòye yìí sí, nítorí Nabali ni orúkọ rẹ̀, bí orúkọ rẹ̀ tí ń jẹ́, bẹ́ẹ̀ náà sì ni ìwà rẹ̀ rí. Oluwa mi, n kò rí àwọn iranṣẹ rẹ nígbà tí wọ́n wá.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 25

Wo Samuẹli Kinni 25:25 ni o tọ