Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 25:26 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA tìkararẹ̀ ni ó ti ká ọ lọ́wọ́ kò láti má ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀ ati láti má gbẹ̀san. Nisinsinyii, oluwa mi, níwọ̀n ìgbà tí OLUWA wà láàyè, gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ ati àwọn tí wọn ń ro ibi sí ọ yóo dàbí Nabali.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 25

Wo Samuẹli Kinni 25:26 ni o tọ