Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 25:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nabali dá àwọn iranṣẹ náà lóhùn pé, “Ta ni Dafidi? Ta ni ọmọ Jese? Ọpọlọpọ iranṣẹ ni ó wà nisinsinyii tí wọn ń sá kúrò ní ọ̀dọ̀ oluwa wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 25

Wo Samuẹli Kinni 25:10 ni o tọ