Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 25:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé kí n wá mú oúnjẹ mi ati omi mi ati ẹran tí mo pa fún àwọn tí wọn ń gé irun aguntan mi, kí n sì gbé e fún àwọn tí n kò mọ ibi tí wọ́n ti wá?”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 25

Wo Samuẹli Kinni 25:11 ni o tọ