Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 14:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu bá pàṣẹ fún àwọn tí wọ́n wà lọ́dọ̀ rẹ̀ pé kí wọ́n ka gbogbo àwọn ọmọ ogun, láti mọ àwọn tí wọ́n jáde kúrò láàrin wọn. Wọ́n bá ka àwọn ọmọ ogun, wọ́n sì rí i pé Jonatani ati ọdọmọkunrin tí ń ru ihamọra rẹ̀ kò sí láàrin wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 14

Wo Samuẹli Kinni 14:17 ni o tọ