Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 14:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ ogun Saulu tí wọn ń ṣọ́nà ní Gibea, ní agbègbè Bẹnjamini, rí i tí àwọn ọmọ ogun Filistini ń sá káàkiri.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 14

Wo Samuẹli Kinni 14:16 ni o tọ