Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 14:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu wí fún Ahija, alufaa pé, “Gbé àpótí Ọlọrun wá níhìn-ín.” Nítorí àpótí Ọlọrun ń bá àwọn ọmọ ogun Israẹli lọ ní àkókò náà.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 14

Wo Samuẹli Kinni 14:18 ni o tọ