Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 14:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀rù ba gbogbo àwọn ará Filistia tí wọ́n wà ní ibùdó, ati àwọn tí wọ́n wà ninu pápá, ati gbogbo eniyan. Àwọn ọmọ ogun Filistini ati àwọn ẹgbẹ́ ogun tí wọ́n ń digun-jalè wárìrì, ilẹ̀ mì tìtì, jìnnìjìnnì sì dà bo gbogbo wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 14

Wo Samuẹli Kinni 14:15 ni o tọ