Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 12:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn wọ́n gbàgbé OLUWA Ọlọrun wọn. Wọ́n jagun, OLUWA sì fi wọ́n lé Sisera, olórí ogun Jabini ọba Hasori lọ́wọ́, àwọn ará Filistia ati ọba Moabu náà sì ṣẹgun wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 12

Wo Samuẹli Kinni 12:9 ni o tọ