Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 12:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, àwọn baba ńlá yín kígbe pe OLUWA fún ìrànlọ́wọ́. Wọ́n ní, ‘A ti ṣẹ̀, nítorí pé a ti kọ OLUWA sílẹ̀, a sì ń sin oriṣa Baali, ati ti Aṣitarotu. Nisinsinyii, gbà wá lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wa, a óo sì máa sìn ọ́.’

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 12

Wo Samuẹli Kinni 12:10 ni o tọ