Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 12:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jakọbu ati ìdílé rẹ̀ lọ sí ilẹ̀ Ijipti, tí àwọn ará Ijipti ń ni wọ́n lára, àwọn baba ńlá yín kígbe pe OLUWA fún ìrànlọ́wọ́, OLUWA sì rán Mose ati Aaroni, wọ́n kó wọn jáde kúrò ní Ijipti. Ó sì mú kí wọ́n máa gbé orí ilẹ̀ yìí.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 12

Wo Samuẹli Kinni 12:8 ni o tọ