Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 23:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sì wí pé, “OLUWA, kò yẹ kí n mu omi yìí, nítorí pé, yóo dàbí ẹni pé ẹ̀jẹ̀ àwọn ọkunrin mẹta yìí, tí wọ́n fi orí la ikú lọ ni mò ń mu.” Nítorí náà, ó kọ̀, kò mu ún.Ìṣẹ̀lẹ̀ yìí jẹ́ ara àwọn nǹkan ìgboyà tí àwọn akọni ọmọ ogun mẹta náà ṣe.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 23

Wo Samuẹli Keji 23:17 ni o tọ