Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 23:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Arakunrin Joabu, tí ń jẹ́ Abiṣai, ọmọ Seruaya ni aṣiwaju fún “Àwọn Ọgbọ̀n Akọni Olókìkí.” Ó fi idà rẹ̀ pa ọọdunrun eniyan, nípa bẹ́ẹ̀, ó di olókìkí láàrin wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 23

Wo Samuẹli Keji 23:18 ni o tọ