Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 23:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn akọni ọmọ ogun mẹta yìí bá fi tipátipá la àgọ́ àwọn ará Filistia kọjá, wọ́n pọn omi láti inú kànga náà, wọ́n sì gbé e wá fún Dafidi. Ṣugbọn Dafidi kọ̀, kò mu ún. Kàkà bẹ́ẹ̀, ó dà á sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹbọ ohun mímú fún OLUWA.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 23

Wo Samuẹli Keji 23:16 ni o tọ