Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 20:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá bèèrè lọ́wọ́ Amasa pé, “Ṣé alaafia ni, arakunrin mi?” Ó fi ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ gbá Amasa ní irùngbọ̀n mú, bí ẹni pé ó fẹ́ fi ẹnu kò ó ní ẹnu.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 20

Wo Samuẹli Keji 20:9 ni o tọ