Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 20:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Amasa kò fura rárá pé idà wà ní ọwọ́ Joabu. Joabu bá gún un ní idà níkùn, gbogbo ìfun rẹ̀ tú jáde. Amasa kú lẹsẹkẹsẹ, láì jẹ́ pé Joabu tún gún un ní idà lẹẹkeji.Joabu ati Abiṣai arakunrin rẹ̀ bá ń lépa Ṣeba lọ.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 20

Wo Samuẹli Keji 20:10 ni o tọ