Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 20:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n dé ibi òkúta ńlá kan, tí ó wà ní Gibeoni, Amasa lọ pàdé wọn. Ẹ̀wù ọmọ ogun ni Joabu wọ̀; ó sán ìgbànú kan, idà rẹ̀ sì wà ninu àkọ̀ lára ìgbànú tí ó ti sán mọ́ ìbàdí. Bí Joabu ti rìn siwaju bẹ́ẹ̀ ni idà yìí bọ́ sílẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 20

Wo Samuẹli Keji 20:8 ni o tọ