Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 19:6 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí pé o fẹ́ràn àwọn tí wọ́n kórìíra rẹ, o sì kórìíra àwọn tí wọ́n fẹ́ràn rẹ. O ti fihàn gbangba pé, àwọn ọ̀gágun ati ọmọ ogun rẹ kò jẹ́ nǹkankan lójú rẹ. Mo ti rí i gbangba lónìí pé, ìbá dùn mọ́ ọ ninu, bí gbogbo wa tilẹ̀ kú, tí Absalomu sì wà láàyè.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 19

Wo Samuẹli Keji 19:6 ni o tọ