Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 19:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Yára dìde, kí o lọ tu àwọn ọmọ ogun ninu; nítorí pé mo fi OLUWA búra pé, bí o kò bá ṣe bẹ́ẹ̀, kò ní ku ẹnìkan ninu wọn pẹlu rẹ ní òwúrọ̀ ọ̀la. Èyí yóo wá burú ju gbogbo ibi tí ó ti bá ọ láti ìgbà èwe rẹ títí di òní lọ.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 19

Wo Samuẹli Keji 19:7 ni o tọ