Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 19:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Joabu bá wọlé tọ ọba lọ, ó wí fún un pé, “O ti dójúti àwọn ọmọ ogun rẹ lónìí, àwọn tí wọ́n gba ẹ̀mí rẹ là, ati ẹ̀mí àwọn ọmọ rẹ, ati ti àwọn aya rẹ, ati àwọn obinrin rẹ;

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 19

Wo Samuẹli Keji 19:5 ni o tọ