Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 15:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò sì tíì pẹ́ pupọ tí o dé, kí ló dé tí o fi fẹ́ máa bá mi káàkiri ninu ìrìnkèrindò mi? Èmi gan-an nìyí, n kò tíì mọ ibi tí mò ń lọ. Pada kí àwọn ará ìlú rẹ gbogbo sì máa bá ọ lọ. OLUWA yóo fẹ́ràn ìwọ náà, yóo sì dúró tì ọ́.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 15

Wo Samuẹli Keji 15:20 ni o tọ