Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 15:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba bá kọjú sí Itai ará Gati, ó sì bi í pé, “Kí ló dé tí o fi ń bá wa lọ? Pada, kí o lọ dúró ti ọba, àlejò ni ọ́, sísá ni o sá kúrò ní ìlú rẹ wá síhìn-ín.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 15

Wo Samuẹli Keji 15:19 ni o tọ