Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 15:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Itai dáhùn pé, “Kabiyesi, mo fi OLUWA búra, bí ẹ̀mí oluwa mi ọba tí ń bẹ láàyè, pé, ibikíbi tí o bá ń lọ ni n óo máa bá ọ lọ, kì báà tilẹ̀ já sí ikú.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 15

Wo Samuẹli Keji 15:21 ni o tọ