Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 14:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni ọba sọ fún Joabu pé, “Mo ti pinnu láti ṣe ohun tí o fẹ́ kí n ṣe. Lọ, kí o sì mú Absalomu, ọmọ mi, pada wá.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 14

Wo Samuẹli Keji 14:21 ni o tọ