Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 14:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Joabu bá wólẹ̀, ó dojúbolẹ̀, ó sì dúpẹ́ lọ́wọ́ ọba, ó ní, “Kabiyesi, nisinsinyii ni èmi iranṣẹ rẹ mọ̀ pé mo ti bá ojurere rẹ pàdé, nítorí pé o ṣe ohun tí mo fẹ́.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 14

Wo Samuẹli Keji 14:22 ni o tọ