Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 12:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Dafidi rí i pé wọ́n ń bá ara wọn sọ̀rọ̀ kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́, ó fura pé ọmọ ti kú. Ó bèèrè lọ́wọ́ wọn pé, “Ṣé ọmọ ti kú ni?”Wọ́n dá a lóhùn pé, “Ó ti kú.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 12

Wo Samuẹli Keji 12:19 ni o tọ