Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 12:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ keje, ọmọ náà kú, ẹ̀rù sì ba àwọn iranṣẹ Dafidi láti sọ fún un pé ọmọ ti kú. Wọ́n ní, “Ìgbà tí ọmọ yìí wà láàyè, a bá Dafidi sọ̀rọ̀, kò dá wa lóhùn. Báwo ni a ṣe fẹ́ sọ fún un pé ọmọ ti kú? Ó lè pa ara rẹ̀ lára.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 12

Wo Samuẹli Keji 12:18 ni o tọ