Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 12:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi bá dìde kúrò ní ilẹ̀, ó wẹ̀, ó fi òróró pa ara rẹ̀, ó pààrọ̀ aṣọ rẹ̀, ó sì lọ sí ilé OLUWA láti jọ́sìn. Lẹ́yìn náà, ó pada sí ilé rẹ̀, ó bèèrè fún oúnjẹ, wọ́n gbé e fún un, ó sì jẹ ẹ́.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 12

Wo Samuẹli Keji 12:20 ni o tọ