Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 44:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwọ ni o fi ọwọ́ ara rẹ lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde fún wọn,tí o sì fi ẹsẹ̀ àwọn baba wa múlẹ̀;o fi ìyà jẹ àwọn orílẹ̀-èdè náà,o sì jẹ́ kí ó dára fún àwọn baba wa.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 44

Wo Orin Dafidi 44:2 ni o tọ