Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 44:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé kì í ṣe idà wọn ni wọ́n fi gba ilẹ̀ náà,kì í ṣe agbára wọn ni wọ́n fi ṣẹgun;agbára rẹ ni; àní, agbára ọwọ́ ọ̀tún rẹ,ati ojurere rẹ;nítorí pé inú rẹ dùn sí wọn.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 44

Wo Orin Dafidi 44:3 ni o tọ