Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ọbadaya 1:13-15 BIBELI MIMỌ (BM)

13. O kì bá tí wọ ìlú àwọn eniyan miní ọjọ́ ìpọ́njú wọn;o kì bá tí fi wọ́n ṣẹ̀sínní ọjọ́ àjálù wọn;o kì bá tí kó wọn lẹ́rùní ọjọ́ ìpọ́njú wọn.

14. O kì bá tí dúró sí oríta,kí o máa mú àwọn tí wọn ń gbìyànjú láti sá àsálà;o kì bá tí fà wọ́n lé àwọn ọ̀tá wọn lọ́wọ́ní ọjọ́ ìpọ́njú wọn.

15. “Ọjọ́ ìdájọ́ OLUWA fẹ́rẹ̀ dé sórí àwọn orílẹ̀-èdè;a óo san án fún ọ, gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ.Ohun tí o bá ṣe, yóo pada sí orí ara rẹ.

Ka pipe ipin Ọbadaya 1