Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ọbadaya 1:14 BIBELI MIMỌ (BM)

O kì bá tí dúró sí oríta,kí o máa mú àwọn tí wọn ń gbìyànjú láti sá àsálà;o kì bá tí fà wọ́n lé àwọn ọ̀tá wọn lọ́wọ́ní ọjọ́ ìpọ́njú wọn.

Ka pipe ipin Ọbadaya 1

Wo Ọbadaya 1:14 ni o tọ