Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ọbadaya 1:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin eniyan mi, bí ẹ ti jìyà ní òkè mímọ́ mi,bẹ́ẹ̀ ni gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè náà yóo jìyà;wọn óo jìyà yóo tẹ́ wọn lọ́rùn,wọn yóo sì wà gẹ́gẹ́ bí ẹni pé wọn kò sí rí.

Ka pipe ipin Ọbadaya 1

Wo Ọbadaya 1:16 ni o tọ